Mo kí ọ, Màríà

Mo kí ọ, Màríà.

O kún fún oore-ọ̀fẹ́.

Olúwa ńbẹ pẹ̀lú rẹ.

Alábùkúnfún ni ìwọ nínú àwọn obìnrin.

Alábùkúnfún sì ni èso inú rẹ, Jésù.

 

Màríà mímọ́, Ìyá Ọlọ́run,

gbàdúrà fún wa, àwa òtòṣì ẹlẹ́ṣẹ̀,

nísìsinyìí àti l'àkókò ikú wa.

Àmín!

  • Aucune note. Soyez le premier à attribuer une note !

Ajouter un commentaire

Anti-spam